1 00:00:00,380 --> 00:00:02,620 Ògún o 2 00:00:03,420 --> 00:00:05,320 Ògún oníreè ọkọ ò mi 3 00:00:05,320 --> 00:00:07,280 Irúnmolè tí-ń rù mìnìmìnì 4 00:00:07,840 --> 00:00:09,520 Òlómi nílé fèjè wè 5 00:00:09,840 --> 00:00:12,020 Òlása nílé fìmọ̀bímoò bora 6 00:00:12,320 --> 00:00:13,740 Ògún aládàá méjì 7 00:00:14,040 --> 00:00:15,360 Ó fìkán sánko, 8 00:00:15,500 --> 00:00:16,660 ó fìkán yènà 9 00:00:16,800 --> 00:00:19,420 Ojó Ògún nfìkòlé òrun bò wá s'ílé ayé 10 00:00:19,560 --> 00:00:21,040 Asa iná ló mú bora 11 00:00:21,320 --> 00:00:23,060 èw'èjè ló wọ̀ sọ́rùn o 12 00:00:23,720 --> 00:00:25,800 Ògún onílé owó ọlọ́nà ọlà 13 00:00:26,120 --> 00:00:28,300 Ògún onílé kángun kàngun òde òrun 14 00:00:28,700 --> 00:00:30,400 Méje l'Ògúuùn mi 15 00:00:30,680 --> 00:00:32,500 Ògún alárá n'í gbajá 16 00:00:32,840 --> 00:00:34,520 Ògún oníreè a gbàgbò 17 00:00:34,820 --> 00:00:36,840 Ògún ìkọlaà a gbà 'gbín 18 00:00:37,080 --> 00:00:39,260 Ògún elémonà n'í gbeèsun'su 19 00:00:39,680 --> 00:00:41,640 Ògún Akìrun á gbà wò àgbò 20 00:00:41,900 --> 00:00:44,720 Ògúùn gbénàgbénà [eran ahun níí je] 21 00:00:45,020 --> 00:00:48,125 Ògúùn mákinde, ti d'Ògún léhìn odi 22 00:00:48,380 --> 00:00:50,660 Bí ò bá gba tápaà gbàbókí 23 00:00:50,980 --> 00:00:52,140 á gbaà húnkùnhúnkùn 24 00:00:52,140 --> 00:00:53,720 á gba tèmbèrí o jàre 25 00:00:54,140 --> 00:00:56,980 mo ní e má bógúnrún fìjà seré 26 00:00:57,520 --> 00:00:59,620 Ògún òlódodo l'Ògún tèmi 27 00:00:59,620 --> 00:01:01,920 Ọmọ Orórínà, ọmọ Tàbúfú 28 00:01:02,580 --> 00:01:06,160 Morú nítorípé l'ójó Ògún kó délé ayé, 29 00:01:06,780 --> 00:01:10,120 Emu ló kó bèrè o ḿgbà tó délè ìrè o 30 00:01:10,480 --> 00:01:12,600 Ògún onílé owó, Olónà olà 31 00:01:13,000 --> 00:01:15,140 Ògún ónile, kángunkàngun òde òrun 32 00:01:15,660 --> 00:01:18,820 Mo ní e má aàbógùn fìjà sére o o 33 00:01:19,280 --> 00:01:24,740 Ara Ògún kan gó gó gó